Àdán

Irú orín wo nì ìwọ ó kọ,
Ní iṣẹ̀jú àáyá́ kí ìjì mi tó wọlé dé?

Nínu ilé ìjọsìn, àwọn àdán ba
S’ ori gbohùngbohùn ní ẹ̀gbẹ̀ àgá ìwàásù.

Tí ó ń túmọ sí wípé, wọ́ ń gbọ́ wa,
Bí àwọ́n igbà àtijọ́.

A’ ń sòrò ẹ̀mí bí àwọn baban ńlá wa
Ṣùgbọ́n mi ò mọ́ ohun ọlọ́ hún gbọ́ yé nìnù rẹ.

Èyí jé, akọ́ kọ́ iyanu tí mo rí,
Wọ́n kò si jẹ̀ oúnjẹ kọn.

Wọ́n fò lọ́ ní àsìko tó súnmó ìgbà tí wọ́n wá,
Ọjọ mètá, lẹhin gba tí a kí irún irọlẹ̀ tán.

Dì àsìkò yí, mi o mọ́ ohún tí awọ́n adán jẹ ò.
Àhọ́n iná ń jó nìnú ẹyin àtùpà.

Lẹ́ hìn àdúrà, a jókòó a sì sọ̀rọ̀ jẹ́ jẹ́ sí àtẹ̀lẹ̀wọ́ wa
Mo dákẹ́, ṣùgbọ́n àwọn àdán ní mó ń wò.

Inú mi dùn nìgbà tí wọn gba ojú fèrèsé jáde,
Padà sí oju ọrun, tí o yẹ àwọ́n oún iyánu.