Etí Òkun

Kété sí omi òkun,
Mó sájú àdurà fún àwọn jagunjagun

Kò sí àmì orúko tàbí ipò
Ni àyà wọn. Ojúlùmọ́ ni wọn

Tàbí kí wo ̣́n jé àwọn oníṣègùn
Tí wọn gbé àwọ́̀ ojú ọlọ́rùn wọ́.

Àwọn ojú oórí t’ó ní itọ́ ka
Ńbẹ ní ìtẹ̀ àwọn jagunjagun.

Ọgbá àwọn òdòdò dá ọgbé,
Mo bàwón lówó léyìn adúrà ná.

Òsè mẹ̀tá sẹ̀yìn,
mo gbá iró ọ̀fọ́

Òrẹ mí kán tí ibà dè mọ́ lè
Tí ofí já okùn ẹ̀mí ẹ̀. Ó jẹ́ ‘kán nínú wọn

O sì wọ ẹ̀wù tí mí o rí ní ọ̀rún rẹ̀ rí
Nìgbá tí mo ṣì wà ní ìlé

Mo pé l’ órukọ rẹ̀,
O í dáhùn, ṣùgbọn pẹ̀lú iyàlẹ́nú

Àpọ̀ ìwé ń bẹ́ ní ẹ̀nu mi
Fún gbogbo ẹ̀ni tí okú.

Ní orí ilẹ̀ koriko kán
Mo sáré tí ẹsẹ̀ mi fí paré.

Omi òkun ti pá gbogbo agbègbé nà ré,
Yíyó oòrùn ni àwọn ènìyàn ń retí.

Ní ihòhò ní etí odò òkun tó kún fún iyọ̀,
It àn o ránti ọjọ́ yi pẹ̀ lú ìsèmi atí ewu ikú

Yíì ó jẹ́ àkọ́ kọ́ irú rẹ, tí wọ́n ó rò pé
Ẹwà fara pẹ́ ìdáró.

Àwọ̀ ara mí ó sì máà kọ yànràn
Pẹ̀lú òrí tí mó fì párá.

Àtẹ́gùn tútù fé làtí orì òkun,
Ríru rẹ o si rọlẹ̀, nígbà tọ́ ‘bá kọlu àpáta.